A GBÉEYÍN G [We Magnify You - Yorùbá]

$7.99
No reviews yet Write a Review
SKU:
MUS-CMF-A-GBEEYIN-GA

A GBÉEYÍN GA jé àkójopò tifun ti àdúrà, orin àtí ìsìn latí owó Dr. Noel Woodroffe ati ilé isé orin Congress.

Ìfihàn tí ó lágbàra yi tí ó jade láti inú okàn ìmore ti àwon ènìyàn káàkiri ayé ti nse àjoyò títóbí, àìlópin àti ògo olórun, iyì àti ìwàbí olórun lórí ilè ayé. Àwon orin wòn yí jé àpere pàtàkì fun ibùsò awon ní ìrìn àjò àjorìn wa.

Ase èyà ti ìgbóhùn sílè tí èdè gèésì ní Elijah centre tíó jé ìsèdá àti òpó múléró ti Congress. Dr. Noel Woodroffe àti ìyàwó rè, June Woodroffe àti àwon ènìyàn mímó ti Elijah centre pèlú àwon tí a yàn káàkiri àwon ìjo wa ní Trinidad àti Tobago ni wón se atókùn ìgbohùn sílè orin yìí.

Àwon akorin àtí olórin káàkiri àgbáyé wá darapò láti se ìgbékalè orin ìmúlò ìsìn ní èdè bíí mérìnlá. Báyì alè gbó ohùn àwon ènìyàn mímó káàkirí àgbáyé bí wón tiúngbé orin ìyìn àti ìbuolá tí ó léwà sókè sí olúwa Jésù Krístì.

Track Listing: